Ajayi Abisola and Olanrewaju Oluwatimileyin also known as Bisola-becca and Aayo Alatileyin (respectively) are friends, young ladies with extremely sonorous voices, lovers of the Gospel, music Ministers,song writers and stage performers. They choose to shine the Light of God with their lives and voices in every way possible.
Digi (Mirror) is a song written and Vocalized to Celebrate, Honor and Appreciate all Fathers in the universe for their unique personality,care and sacrifices towards their children, Helpmates and everyone around them.
We(the dignified Digi crooners) recognize the great importance of fatherhood in totality,and we celebrate the fathers in our world who understand and act according to the truth that it is not enough to sow the seeds of human life,and that vigilance and intentional nurturing of the plants (children) is required.
A loud applause to all Fathers out there.
May their rewards be duly received.
This is Dígí- Mirror… Every father needs to listen to this.
Download From
Digital Store
“`Digi“`
My father goes further
To take me further
You’re more than a Father
You’re such a wonder
Er er er er er er
A golden icon you are
I love you father mi
I love you father mi
Chorus
Baba ẹni ni baba ẹni
Digi eni ni Digi eni
Oloko to wa ni waye
E ma ku isẹ
Ise nla lese
Iṣẹ ribiribi
Sadankata re
(Mo ki o baba mi o)
Baba eni ni baba eni
(Ku ise)
Digi eni ni Digi eni
(A mo riri re)
Oloko to wa ni waye
(E ma se)
E ma ku isẹ
(E ku isẹ ribiribi)
Ise nla le se
(Nigba ojo nigba erun)
Ise ribiribi
(Ko su o ri,e se oooo)
Sadankata re
Interlude
Tani baba? Baba ni digi
Baba lade lori aya lori omo
Alagbara akikanju okunrin
E ma ku isẹ o
E ku oro mi
Baba laagun a sise sise
K’ẹmi le jeun,k’ẹmi le woso
Ki n tun le ka’we de’bi giga opo
Itoju re pọ,aabo re o pe’ye
Mo gb’osuba fun ọpọ
Sadankata re
Chorus
(Eh eh e ba n ki baba mi)
Baba eni ni baba eni
(Baba rere Digi mi)
Digi eni ni Digi eni
(Eheheh Oloko to wa ni waye e se)
Oloko to wa ni waye
(Ku ise o)
E ma ku ise
Ise nla le se
(Ise ribiribi ribiribi)
Ise ribiribi
(Eheheh sadankata re)
Sadankata re
My father goes farther
That I may further
You no dey too slumber
You be Almighty replica
I love the way you Father mi
Gba’ni ma gba beyen
Wetin I no see for tree top
You see am for sitting room
Digi nla,Digi rere
Thank you for all you do
My golden icon you are
I love you father mi
(Digi mi)
Chorus
Baba eni ni baba eni
(Baba mi)
Digi eni ni Digi eni
(Eheheh e ba n ki mirror mi)
Oloko to wa ni waye
(Eeeeh e ma se baba mi o)
E ma ku ise
(Mo dupe dupe)
Ise nla le se
(E se eh eh)
Ise ribiribi
(Eheheh sadankata re)
Sadankata re
Digi nla ni Digi – Digi nla ni Digi
Digi to rinitan,to ju ni lo – digi nla ni Digi
A mo o ni atokepe aponmo sokan – digi nla ni Digi
Ko gbodo fo,ko se ropo – Digi nla ni Digi
Wa pe pe pe,ara a le koko ko – digi nla ni digi
Baba alaibikita ki le ni mowi? – Digi nla ni Digi
Itoju aya omo o se pataki o – Digi nla ni Digi
Asaaju le je,lay a good example ooo – digi nla ni Digi
Nnaso u’bana (I love you father)
Afum gi naya Nnam(I love you my father)
Digi nla ni Digi
Digi o Digi o Digi o – Digi nla ni Digi
Digi le je e e eh – Digi nla ni Digi
A gbe o gege bi eyin – Digi nla ni Digi.